EWÌ SỌ̀RỌ̀ SÓKÈ

EWÌ SỌ̀RỌ̀ SÓKÈ

Paperback (13 Apr 2021) | Afrikaans

Save $5.67

  • RRP $41.63
  • $35.96
Add to basket

Includes delivery to the United States

10+ copies available online - Usually dispatched within 7 days

Publisher's Synopsis

EWÌ SỌ`RỌ` SO´KE` Ó jẹ´ ohùn ìdùnnú fún mí púpọ` láti kọ ìwé àkójọpọ` ewì yìí. Àwọn ewì jẹ ohun àbálàye tí ó jẹ ọmọ Yorùbá lógún. Ní ayé àtijọ´ ní ilè Yorùbá, ò un ni àwọn bàbá-nlá wa máa n lò fún ìmò?, ìmò?ràn àti ẹ`kọ´, ṣùgbó?n won kìí kọọ´ sílẹ` nítorí pé, wọn kò ní ìmò? mò?ó?kọ-mò?ó?kà rárá. Orísírísí àwọn ewì ni ó wa, Èrò ọkàn mí ní pé a ó gbàdùn ìwé àkójọpọ` ewì yìí. "Ewì Sọ`rọ` Sókè!" ni àkọlé Ìwé Ìṣípayá Ewi Yorùbá yìí (Poetry On Speak Up!). Àkọlé ìwé yìí jẹ jáde nínú ọ`rọ` àwọn ọ`dọ´ Nàíjíríà (A popular phrase that has informally become the name of the millennial slang of generations in Nigeria). Àwọn ọ`dọ´ ṣe ìwọde #EndSARS ní Orílẹ`-èdè Nàíjíríà ní ìpínlè Èkó, Ekiti, Ọ`yọ´, Ondo, Osun, Kwara ati Abuja lati bá àwọn olórí àti àwọn ọmọ ilu sọ`rọ` ní ọdún 2020. Kí ni ìtumọ` "Sọ`rọ` Sókè" àti Ìwọ´de tí àwọn ọ`dọ´ n ṣe àgbékalẹ` rẹ` yìí? Wó?n fi Ìwọ´de #EndSARS yìí sọ pé kí àwọn Ọlọpa má ṣe pa àwọn ará ìlú mọ´, pàtàkì jù lọ àwọn ọ`dọ´ àti pé kí olúkúlùkù sọ àwọn è?dùn ọkàn wọn gbogbo jáde ni orílẹ`-èdè NÀÍJÍRÍÀ. Naijiria ni orílè-èdè tí ó ní ibùgbé púpò jùlọ ní Afrika, ó tún jẹ´ ìkẹjọ ní àgbáyé, bẹ si ní ó jẹ´ orílẹ`-èdè tó ní àwọn ènìyàn dúdú jùlọ pè?lú.

Book information

ISBN: 9786200622136
Publisher: KS Omniscriptum Publishing
Imprint: Globeedit
Pub date:
Language: Afrikaans
Number of pages: 76
Weight: 122g
Height: 229mm
Width: 152mm
Spine width: 5mm